IMG_20160705_143507

DOWNLOAD MUSIC


Chorus:
Ogo Ola re
Aiku, aisa, aidibaje
Ogo Ola re
Ayeraye o, Oba

Verse 1:
Ka jumo gb’oruko Jesu ga
(Iwo l’oba, Iwo l’oba)
Ki gbogbo angeli juba re
(Iwo l’oba, Iwo l’oba)
Let the earth declare your majesty, let them know that you are God
(You are God…)
Ki a dobale fun oga ogo, se’bi’wo lo tunmise eh eh ah

Verse 2:
S’eni ki n maa bo?
S’eni ki n wa?
Ma bo bata, bee tie ni n bo
Eyin l’Oba ajiki, ajiyin, ajiun
Eyin l’Oba ajibo
Eru re n ba mi ooo
Mio to w’oju re
Mio to k’orin re
Mio to gb’Ogo re
Mio to ooo
Eru re n ba mi ooo
Eni to O o si
Eru re n ba mi ooo

Vamp:
(Se l’Oba awon oba)
Oba awon oba
Olorun awon omo ogun
Gbingbiniki, awuwo ma se gbe
Erujeje ti n m’igbo kijikiji

Ko i to ooo
Ijo ti mo jo l’ana (ein)
Orin ti mo ko l’ana (beeni)
Ope ti mo gbe l’ana (yes)
Babatunmise! (yeah)
Ko i to ooooo

Outro:
Ogo Ola re o
Aiku, aisa, aidibaje o
Ogo Ola re o
Ayeraye o, Oba

 

DOWNLOAD MUSIC